Ni abala yi a o ma mu to eti igbo yin alaye lori Usul al-Fiqh ati Maqasidu As-Shari’ah.
Eleyi je iforowero lori iwe ti akole re n je “Shariah Intelligence” lati Da’wah Institute of Nigeria, Islamic Education Trust, Minna, Nigeria.
Awon olumo ninu eto yi ni:
Ustadh Ismail AbdulKadir
Ustadh Ahmad Nafi’i Al-jawhari
Ustadh Dawud AbdulKareem Zakariyyah, ati
Alh. Ibrahim Yahya