Ni abala yi a o ma mu to eti igbo yin alaye lori Usul al-Fiqh ati Maqasidu As-Shari’ah. Eleyi je iforowero lori iwe ti akole re n je “Shariah Intelligence” lati Da’wah Institute of Nigeria, Islamic Education Trust, Minna, Nigeria. Awon olumo ninu eto yi ni: Ustadh Ismail AbdulKadir Ustadh Ahmad Nafi’i Al-jawhari Ustadh Dawud AbdulKareem Zakariyyah, ati Alh. Ibrahim Yahya